ọ̀rọ̀-ìṣe
noun
/ɔ̀.ɾɔ̀.ì.ʃē/
IS (alternative), ọ̀rọ̀ ìṣe (alternative)
Definitions
-
verb
Kí ni ìtumọ̀ ọ̀rọ̀-ìṣe èdè Gẹ̀ẹ́sí "to meet"? What is the meaning of the English verb, "to meet"?Oriṣìí Ọ̀rọ̀-ìṣe (Verb Types) Oríṣìí ọ̀rọ̀-ìṣe (verb) mẹ́ta ni ó wà. Àwọn náà ni aláìgbàbọ̀ (intransitive), asopọ̀ (linking) àti agbàbọ̀ (transitive). Verb Types There are three types of verbs. They are intransitive verbs, linking verbs, and transitive verbs.Inú ọ̀rọ̀ ìṣe èdè Hébérù tó túmọ̀ sí “láti di” ni orúkọ náà, Jèhófà ti wá. The name Jehovah comes from a Hebrew verb that means “to become.”Related wordsọ̀rọ̀-anítumọ̀-àdámọ́ọ̀rọ̀-arọ́pò-orúkọọ̀rọ̀-asopọ̀ọ̀rọ̀-atọ́kùn ọ̀rọ̀-orúkọnoun 2 entries are spelled “ọ̀rọ̀-orúkọ”, and the list this came from doesn't say which one is meant — we've linked to the first. ọ̀rọ̀-orúkọ noun ọ̀rọ̀ orúkọ alternative form of ọ̀rọ̀-orúkọ ọ̀rọ̀-ọgbọ́nọ̀rọ̀-àfetíyá ọ̀rọ̀ àkànlònoun 2 entries are spelled “ọ̀rọ̀ àkànlò”, and the list this came from doesn't say which one is meant — we've linked to the first. ọ̀rọ̀ àkànlò idiom, idiomatic phrase ọ̀rọ̀-àkànlò alternative form of ọ̀rọ̀ àkànlò (“idiom”) ọ̀rọ̀-àpọ́nléọ̀rọ̀-àpèjúweọ̀rọ̀-àyálònounọ̀rọ̀-áfojúyáọ̀rọ̀-èdèọ̀rọ̀-ìró-ìtumọ̀ọ̀rọ̀-ìrótumọ̀Kinds of thisagbẹ̀yìn ọ̀rọ̀-ìṣeaṣáájú ọ̀rọ̀-ìṣeọ̀rọ̀-ìṣe abọ́déọ̀rọ̀-ìṣe abáṣelọọ̀rọ̀-ìṣe agbàbọ̀ọ̀rọ̀-ìṣe alápèpadàọ̀rọ̀-ìṣe aláìbáṣelọọ̀rọ̀-ìṣe aláìgbàbọ̀ọ̀rọ̀-ìṣe asolùwàdàbọ̀ọ̀rọ̀-ìṣe aṣẹpọ́nọ̀rọ̀-ìṣe aṣẹ̀dá-àpèjúweọ̀rọ̀-ìṣe aṣẹ̀yánọ̀rọ̀-ìṣe aṣokùn-ùnfàọ̀rọ̀-ìṣe aṣàpọ́nléọ̀rọ̀-ìṣe aṣàpèjúweọ̀rọ̀-ìṣe aṣèròyìnọ̀rọ̀-ìṣe ayẹ̀rúnọ̀rọ̀-ìṣe ẹlẹ́lànounọ̀rọ̀-ìṣe kíkúnọ̀rọ̀-ìṣe oníbọ̀ọ̀rọ̀-ìṣe ọ̀bọ̀rọ́ọ̀rọ̀-ìṣe àkànmórúkọọ̀rọ̀-ìṣe àrànmásọdorúkọọ̀rọ̀-ìṣe àsínpọ̀ọ̀rọ̀-ìṣe ìmọ-nǹkan
Etymology
From ọ̀rọ̀ (“word”) + ìṣe (“action”), literally “action word”.
Used in
Source: Wiktionary,
where this word is spelled “ọrọ-iṣe”.
Reference:
en-ọrọ-iṣe-yo-noun-aAb4ahfw